Ìfihàn 14:17 BMY

17 Ańgẹ́lì mìíràn sì tí inú tẹmpílì tí ń bẹ ni ọ̀run jáde wá, òun pẹ̀lú sì ní dòjé mímú, kan.

Ka pipe ipin Ìfihàn 14

Wo Ìfihàn 14:17 ni o tọ