Ìfihàn 14:19 BMY

19 Ańgẹ́lì náà sì tẹ dòjé rẹ̀ bọ ilẹ́ ayé, ó sì gé àjàrà ilẹ́-ayé, ó sì kó o lọ sínú ìfúntì, ìfúntí ńlá ìbínú Ọlọ́run.

Ka pipe ipin Ìfihàn 14

Wo Ìfihàn 14:19 ni o tọ