Ìfihàn 15:7 BMY

7 Àti ọ̀kan nínú àwọn ẹ̀dá alààyè mẹ́rin náà fi àgbàda wúrà méje fún àwọn ańgẹ́lì méje náà, tí ó kún fún ìbínú Ọlọ́run, ẹni tí ń bẹ láàyè láé àti láéláé.

Ka pipe ipin Ìfihàn 15

Wo Ìfihàn 15:7 ni o tọ