Ìfihàn 17:7 BMY

7 Ańgẹ́lì sì wí fún mi pé, “Nítorí kí ni ẹnu ṣe yà ọ́? Èmi ó sọ ti ìjìnlẹ̀ obìnrin náà fún ọ, àti ti ẹranko tí ó gùn, ti ó ní orí méje àti ìwo mẹ́wàá.

Ka pipe ipin Ìfihàn 17

Wo Ìfihàn 17:7 ni o tọ