2 Ó sì kígbe ní ohùn rara, wí pé:“Bábílónì ńlá ṣubú! Ó ṣubú!Ó sì di ibùjókòó àwọn ẹ̀mí ẹ̀ṣù,àti ihò ẹ̀mí àìmọ́ gbogbo,àti ilé ẹyẹ àìmọ́ gbogbo,àti ti ẹyẹ ìríra.
Ka pipe ipin Ìfihàn 18
Wo Ìfihàn 18:2 ni o tọ