21 Ańgẹ́lì alágbára kan sì gbé òkúta kan sókè, ó dàbí ọlọ ńlá, ó sì jù ú sínú òkun, wí pé:“Báyìí ní a ó fi agbára ńlábíi Bábílónì ìlú ńlá ni wó,a kì yóò sì rí i mọ́ láé.
Ka pipe ipin Ìfihàn 18
Wo Ìfihàn 18:21 ni o tọ