Ìfihàn 18:8 BMY

8 Nítorí náà, ní ìjọ kan ni ìyọnu rẹ̀ yóò dé,ìkú, àti ìbìnújẹ́, àti ìyàn;a ó sì fi iná sun ún pátapáta:nítorí pé alágbára ni Olúwa Ọlọ́run tí ń ṣe ìdájọ́ rẹ̀.

Ka pipe ipin Ìfihàn 18

Wo Ìfihàn 18:8 ni o tọ