Ìfihàn 19:11 BMY

11 Mo sì rí ọ̀run sí sílẹ̀, sì wò ó, ẹsin funfun kan; ẹni tí ó jókòó lórí rẹ̀ ni à ń pè ní Olódodo àti Olóòótọ́, nínú òdodo ni ó sì ń ṣe ìdájọ́, tí ó ń jagun.

Ka pipe ipin Ìfihàn 19

Wo Ìfihàn 19:11 ni o tọ