Ìfihàn 19:14 BMY

14 Àwọn ogun tí ń bẹ ní ọrùn tí a wọ̀ ní aṣọ ọ̀gbọ̀ wíwẹ́, funfun àti mímọ́, sì ń tọ̀ ọ́ lẹ̀yìn lórí ẹ̀sin funfun.

Ka pipe ipin Ìfihàn 19

Wo Ìfihàn 19:14 ni o tọ