Ìfihàn 19:19 BMY

19 Mo sì rí ẹranko náà àti àwọn ọba ayé, àti àwọn ogun wọn tí a gbájọ láti bá ẹni tí ó jókòó lórí ẹsin náà àti ogun rẹ̀ jagun.

Ka pipe ipin Ìfihàn 19

Wo Ìfihàn 19:19 ni o tọ