Ìfihàn 2:11 BMY

11 Ẹni tí ó bá ní etí kí ó gbọ́ ohun tí Ẹ̀mí ń sọ fún àwọn ìjọ. Ẹni tí ó bá sẹ́gun kì yóò farapa nínú ikú kejì.

Ka pipe ipin Ìfihàn 2

Wo Ìfihàn 2:11 ni o tọ