Ìfihàn 2:22 BMY

22 Nítorí náà, èmi ó gbé e sọ sí orí àkéte, àti àwọn tí ń bá a ṣe panṣágà ni èmi ó fi sínú ìpọ́njú ńlá, bí kò ṣe bí wọ́n bá ronúpìwàdà iṣẹ́ wọn.

Ka pipe ipin Ìfihàn 2

Wo Ìfihàn 2:22 ni o tọ