Ìfihàn 20:2 BMY

2 O sì di Dírágónì náà mú, ejò àtijọ́ nì, tí í ṣe èṣù, àti Sàtánì, ó sì dè é ní ẹgbẹ̀rún ọdún.

Ka pipe ipin Ìfihàn 20

Wo Ìfihàn 20:2 ni o tọ