1 Mo sì rí ọ̀run titun kan àti ayé titun kan: nítorí pé ọ̀run ti ìṣáajú àti ayé ìṣáajú ti kọjá lọ; òkun kò sì sí mọ́.
Ka pipe ipin Ìfihàn 21
Wo Ìfihàn 21:1 ni o tọ