Ìfihàn 22:1 BMY

1 Ó sì fi odò omi ìyè kan hàn mi, tí ó mọ́ bí Kírísítalì, tí ń tí ibi ìtẹ́ Ọlọ́run àti tí Ọ̀dọ́-Àgùntàn jáde wá,

Ka pipe ipin Ìfihàn 22

Wo Ìfihàn 22:1 ni o tọ