Ìfihàn 22:15 BMY

15 Nítorí ni òde ni àwọn ajá gbé wà, àti àwọn oṣó, àti àwọn àgbérè, àti àwọn apànìyàn, àti àwọn abọ̀rìṣà, àti olúkúlùkù ẹni tí ó fẹ́ràn èké tí ó sì ń hùwà èké.

Ka pipe ipin Ìfihàn 22

Wo Ìfihàn 22:15 ni o tọ