Ìfihàn 22:5 BMY

5 Òru kì yóò sí mọ́; wọn kò sì ní wa ìmọ́lè fìtílà, tàbí ìmọ́lẹ̀ oòrùn; nítorí pé Olúwa Ọlọ́run ni yóò tan ìmọ́lẹ̀ fún wọn: wọn ó sì máa jọba láé àti láéláé.

Ka pipe ipin Ìfihàn 22

Wo Ìfihàn 22:5 ni o tọ