Ìfihàn 3:14 BMY

14 “Àti sí áńgẹ́lì ìjọ ní Láódékíá kọ̀wé:Ọ̀rọ̀ wọ̀nyí ni ẹni tí ń jẹ́ Àmín wí, ẹlẹ́rìí olódodo àti olóòótọ́, olórí ìṣẹ̀dá Ọlọ́run:

Ka pipe ipin Ìfihàn 3

Wo Ìfihàn 3:14 ni o tọ