3 Ẹni tí ó sì jókòó náà dàbí òkúta jásípérì àti sádíúsì lójú. Ni àyíká ìtẹ́ náà ni òṣùmàrè kan wà tí ó dàbí òkúta émérádì lójú.
Ka pipe ipin Ìfihàn 4
Wo Ìfihàn 4:3 ni o tọ