Ìfihàn 6:16 BMY

16 Wọ́n sì ń wí fún àwọn òkè àti àwọn àpáta náà pé, “Ẹ wó lù wá, kí ẹ sì fi wá pamọ́ kúrò lójú ẹni tí ó jókòó lórí ìtẹ́, àti kúrò nínú ìbínú Ọ̀dọ́-Àgùntàn náà:

Ka pipe ipin Ìfihàn 6

Wo Ìfihàn 6:16 ni o tọ