Ìfihàn 6:9 BMY

9 Nígbà tí ó sì ṣí èdìdì karùn ún, mo rí lábẹ́ pẹpẹ, ọkàn àwọn tí a ti pa nítorí ọ̀rọ̀ Ọlọ́run, àti nítorí ẹ̀rí tí wọ́n dìmú:

Ka pipe ipin Ìfihàn 6

Wo Ìfihàn 6:9 ni o tọ