17 Nítorí òdọ̀-Àgùntàn tí ń bẹ ni àárin ìtẹ́ náà ni yóò máa ṣe Olùṣọ́-Àgùntàn wọn,tí yóò sì máa ṣe amọ̀nà wọn sí ibi orísun omi ìyè:Ọlọ́run yóò sì nu omijé gbogbo nù kúrò ni ojú wọn.”
Ka pipe ipin Ìfihàn 7
Wo Ìfihàn 7:17 ni o tọ