Ìfihàn 8:10 BMY

10 Ańgẹ́lì kẹ́ta sì fún ìpè tirẹ̀, ìràwọ̀ ńlá kan tí ń jó bí fìtílà sì bọ́ láti ọ̀run wá, ó sì bọ́ sórí ìdámẹ̀ta àwọn odò ṣíṣàn, àti sórí àwọn orísun omi;

Ka pipe ipin Ìfihàn 8

Wo Ìfihàn 8:10 ni o tọ