Ìfihàn 9:2 BMY

2 Ó sì sí ihò ọ̀gbun náà, èéfín sì rú jáde láti inú ihò náà wá, bí èèfín ìléru ńlá, òòrùn àti ojú sánmà sì ṣóòkùn nítorí èéfín ihò náà.

Ka pipe ipin Ìfihàn 9

Wo Ìfihàn 9:2 ni o tọ