Ìfihàn 9:5 BMY

5 A sì pàṣẹ fún wọn pé, kí wọn má ṣe pa wọ́n, ṣùgbọ́n kí a dá wọn ni oró ni oṣù marùn-ún: oró wọn sì dàbí oró àkéekèe, nígbà tí o bá ta ènìyàn.

Ka pipe ipin Ìfihàn 9

Wo Ìfihàn 9:5 ni o tọ