Jòhánù 1:12 BMY

12 Ṣùgbọ́n iye àwọn tí ó gbà á, àní àwọn náà tí ó gbà orúkọ rẹ̀ gbọ́, àwọn ni ó fi agbára fún láti di ọmọ Ọlọ́run;

Ka pipe ipin Jòhánù 1

Wo Jòhánù 1:12 ni o tọ