Jòhánù 1:31 BMY

31 Èmi gan-an kò sì mọ̀ ọ́n, ṣùgbọ́n ìdí tí mo fi wá ń fi omi ṣe ìtẹ̀bọmi ni kí a lè fi í hàn fún Ísírẹ́lì.”

Ka pipe ipin Jòhánù 1

Wo Jòhánù 1:31 ni o tọ