Jòhánù 1:37 BMY

37 Nígbà tí àwọn ọmọ-ẹ̀yìn méjì náà sì gbọ́ ohun tí ó wí yìí, wọ́n bẹ̀rẹ̀ sì í tọ Jésù lẹ́yìn.

Ka pipe ipin Jòhánù 1

Wo Jòhánù 1:37 ni o tọ