Jòhánù 10:1 BMY

1 “Lóòótọ́, lóòótọ́ ni mo wí fún yín, Ẹni tí kò bá gba ẹnu ọ̀nà wọ inú agbo àgùntàn, ṣùgbọ́n tí ó bá gba ibòmíràn gun òkè, Òun náà ni olè àti ọlọ́sà.

Ka pipe ipin Jòhánù 10

Wo Jòhánù 10:1 ni o tọ