Jòhánù 10:12 BMY

12 Ṣùgbọ́n alágbàṣe, tí kì í ṣe olùṣọ́ àgùntàn, ẹni tí àwọn àgùntàn kì í ṣe tirẹ̀, ó rí ìkokò ń bọ̀, ó sì fi àgùntàn sílẹ̀, ó sì fọ́n wọn ká kiri.

Ka pipe ipin Jòhánù 10

Wo Jòhánù 10:12 ni o tọ