Jòhánù 10:18 BMY

18 Ẹnìkan kò gbà á lọ́wọ́ mi, ṣùgbọ́n mo fi í lélẹ̀, mo sì lágbára láti tún gbà á. Àṣẹ yìí ni mo ti gbà wá láti ọ̀dọ̀ Baba mi.”

Ka pipe ipin Jòhánù 10

Wo Jòhánù 10:18 ni o tọ