Jòhánù 10:4 BMY

4 Nígbà tí ó bá sì ti mú àwọn àgùntàn tirẹ̀ jáde, yóò ṣíwájú wọn, àwọn àgùntàn yóò sì máa tọ̀ ọ́ lẹ́yìn: nítorí tí wọ́n mọ ohùn rẹ̀.

Ka pipe ipin Jòhánù 10

Wo Jòhánù 10:4 ni o tọ