Jòhánù 10:40 BMY

40 Ó sì tún kọjá lọ sí apá kéjì Jodánì sí ibi tí Jòhánù ti kọ́kọ́ ń bamítísì; níbẹ̀ ni ó sì jókòó.

Ka pipe ipin Jòhánù 10

Wo Jòhánù 10:40 ni o tọ