Jòhánù 11:16 BMY

16 “Nítorí náà Tómásì, ẹni tí à ń pè ní Dídímù, wí fún àwọn ọmọ-ẹ̀yìn ẹgbẹ́ rẹ̀ pé, Ẹ jẹ́ kí àwa náà lọ, kí a lè bá a kú pẹ̀lú.”

Ka pipe ipin Jòhánù 11

Wo Jòhánù 11:16 ni o tọ