Jòhánù 11:38 BMY

38 Nígbà náà ni Jésù tún kérora nínú ara rẹ̀, ó wá sí ibojì, ó sì jẹ́ ihò, a sì gbé òkúta lé ẹnu rẹ̀.

Ka pipe ipin Jòhánù 11

Wo Jòhánù 11:38 ni o tọ