Jòhánù 11:4 BMY

4 Nígbà tí Jésù sì gbọ́, ó wí pé, “Àìsàn yìí kì í ṣe sí ikú, ṣùgbọ́n fún Ògo Ọlọ́run, kí a lè yin Ọmọ Ọlọ́run lógo nípasẹ̀ rẹ̀.”

Ka pipe ipin Jòhánù 11

Wo Jòhánù 11:4 ni o tọ