Jòhánù 11:49 BMY

49 Ṣùgbọ́n Káyáfà, ọ̀kan nínú wọn, ẹni tí í ṣe olórí àlùfáà ní ọdún náà, ó wí fún wọn pé, “Ẹ̀yin kò mọ ohunkóhun rárá!

Ka pipe ipin Jòhánù 11

Wo Jòhánù 11:49 ni o tọ