Jòhánù 11:56 BMY

56 Nígbà náà ni wọ́n ń wá Jésù, wọ́n sì ń bá ara wọn sọ̀, bí wọ́n ti dúró ní tẹ́mpílì, wí pé, “Ẹ̀yin ti rò ó sí? Pé kì yóò wá sí àjọ?”

Ka pipe ipin Jòhánù 11

Wo Jòhánù 11:56 ni o tọ