Jòhánù 11:6 BMY

6 Nítorí náà, nígbà tí ó ti gbọ́ pé, ara rẹ̀ kò dá, ó gbé ọjọ́ méjì sí i níbìkan náà tí ó gbé wà.

Ka pipe ipin Jòhánù 11

Wo Jòhánù 11:6 ni o tọ