Jòhánù 11:8 BMY

8 Àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀ sì wí fún un pé, “Rábì, ní àìpẹ́ yìí ni àwọn Júù ń wá ọ̀nà láti sọ ọ́ ní òkúta; ìwọ sì tún padà lọ síbẹ̀?”

Ka pipe ipin Jòhánù 11

Wo Jòhánù 11:8 ni o tọ