Jòhánù 12:11 BMY

11 Nítòrí pé nípasẹ̀ rẹ̀ ni ọ̀pọ̀ nínú àwọn Júù jáde lọ, wọ́n sì gbà Jésù gbọ́.

Ka pipe ipin Jòhánù 12

Wo Jòhánù 12:11 ni o tọ