Jòhánù 12:17 BMY

17 Nítorí náà, ìjọ ènìyàn tí ó wà lọ́dọ̀ rẹ̀ nígbà tí wọ́n gbọ́ pé Lásárù jáde nínú ibojì rẹ̀, tí ó sì jí i dìde kúrò nínú òkú, jẹ́rí sí i.

Ka pipe ipin Jòhánù 12

Wo Jòhánù 12:17 ni o tọ