Jòhánù 12:24 BMY

24 Lóòótọ́, lóòótọ́ ni mo wí fún yín, bí kò ṣe pé àlìkámà bá bọ́ sí ilẹ̀, tí ó bá sì kú, ó wà ní òun nìkan; ṣùgbọ́n bí ó bá kú, a sì so ọ̀pọ̀lọpọ̀ èso.

Ka pipe ipin Jòhánù 12

Wo Jòhánù 12:24 ni o tọ