Jòhánù 12:27 BMY

27 “Ní ìsinsin yìí ni a ń pọ́n ọkàn mi lójú; kínni èmi ó sì wí? ‘Baba, gbà mí kúrò nínú wákàtí yìí’? Rárá, ṣùgbọ́n nítorí èyì ni mo ṣe wá sí wákàtí yìí.

Ka pipe ipin Jòhánù 12

Wo Jòhánù 12:27 ni o tọ