Jòhánù 12:29 BMY

29 Nítorí náà ìjọ ènìyàn tí ó dúró níbẹ̀, tí wọ́n sì gbọ́ ọ, wí pé, àrá ń sán: àwọn ẹlòmíràn wí pé, “Ańgẹ́lì kan ni ó ń bá a sọ̀rọ̀.”

Ka pipe ipin Jòhánù 12

Wo Jòhánù 12:29 ni o tọ