Jòhánù 12:38 BMY

38 Kí ọ̀rọ̀ wòlíì Ìsàíàh lè ṣẹ, èyí tí ó sọ pé:“Olúwa, tani ó gba ìwàásù wa gbọ́Àti ta ni a sì fi apá Olúwa hàn fún?”

Ka pipe ipin Jòhánù 12

Wo Jòhánù 12:38 ni o tọ