Jòhánù 12:40 BMY

40 “Ó ti fọ́ wọn lójú,Ó sì ti sé àyà wọn le;Kí wọn má baà fi ojú wọn rí,Kí wọn má ba à fi ọkàn wọn mọ̀,Kí wọn má baà yípadà, kí wọn má baà mú wọn láradá.”

Ka pipe ipin Jòhánù 12

Wo Jòhánù 12:40 ni o tọ