Jòhánù 12:50 BMY

50 Èmi sì mọ̀ pé ìyè àìnípẹ̀kun ni òfin rẹ̀: nítorí náà, àwọn ohun tí mo bá wí, gẹ́gẹ́ bí Baba ti sọ fún mi, bẹ́ẹ̀ ni mo wí!”

Ka pipe ipin Jòhánù 12

Wo Jòhánù 12:50 ni o tọ