Jòhánù 13:10 BMY

10 Jésù wí fún un pé, “Ẹni tí a wẹ̀ kò tún fẹ́ ju kí a san ẹṣẹ̀ rẹ̀, ṣùgbọ́n ó mọ́ níbi gbogbo: ẹ̀yin sì mọ́, ṣùgbọ́n kì í ṣe gbogbo yín.”

Ka pipe ipin Jòhánù 13

Wo Jòhánù 13:10 ni o tọ