Jòhánù 13:12 BMY

12 Nítorí náà lẹ́yìn tí ó wẹ ẹṣẹ̀ wọn tán, tí ó sì ti mú agbádá rẹ̀, tí ó tún jókòó, ó wí fún wọn pé, “Ẹ̀yin mọ ohun tí mo ṣe sí yín bí?

Ka pipe ipin Jòhánù 13

Wo Jòhánù 13:12 ni o tọ